2 Sámúẹ́lì 15:37 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 37 Nítorí náà, Húṣáì, ọ̀rẹ́* Dáfídì,+ wá sínú ìlú bí Ábúsálómù ṣe ń wọ Jerúsálẹ́mù. 1 Kíróníkà 27:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Áhítófẹ́lì+ jẹ́ agbani-nímọ̀ràn ọba, Húṣáì+ tó jẹ́ Áríkì sì ni ọ̀rẹ́* ọba.