-
1 Àwọn Ọba 5:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000) lára wọn ló máa ń rán lọ sí Lẹ́bánónì lóṣooṣù láti gba iṣẹ́ lọ́wọ́ ara wọn. Wọ́n á lo oṣù kan ní Lẹ́bánónì, wọ́n á sì lo oṣù méjì ní ilé wọn; Ádónírámù+ sì ni olórí àwọn tí ọba ní kó máa ṣiṣẹ́ fún òun.
-