1 Àwọn Ọba 1:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Àmọ́ àlùfáà Sádókù,+ Bẹnáyà+ ọmọ Jèhóádà, wòlíì Nátánì,+ Ṣíméì,+ Réì àti àwọn akíkanjú jagunjagun Dáfídì+ kò ti Ádóníjà lẹ́yìn.
8 Àmọ́ àlùfáà Sádókù,+ Bẹnáyà+ ọmọ Jèhóádà, wòlíì Nátánì,+ Ṣíméì,+ Réì àti àwọn akíkanjú jagunjagun Dáfídì+ kò ti Ádóníjà lẹ́yìn.