Oníwàásù 2:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Kò sóhun tó dáa fún èèyàn ju pé kó jẹ, kó mu, kó sì gbádùn* iṣẹ́ àṣekára rẹ̀.+ Èyí pẹ̀lú ni mo ti rí pé ó wá láti ọwọ́ Ọlọ́run tòótọ́,+
24 Kò sóhun tó dáa fún èèyàn ju pé kó jẹ, kó mu, kó sì gbádùn* iṣẹ́ àṣekára rẹ̀.+ Èyí pẹ̀lú ni mo ti rí pé ó wá láti ọwọ́ Ọlọ́run tòótọ́,+