1 Àwọn Ọba 5:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Àmọ́ ní báyìí, Jèhófà Ọlọ́run mi ti fún mi ní ìsinmi yí ká.+ Kò sí alátakò kankan, láburú kankan ò sì ṣẹlẹ̀.+ 1 Kíróníkà 22:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Wò ó! Wàá bí ọmọkùnrin kan+ tó máa jẹ́ ẹni àlàáfíà,* màá sì fún un ní ìsinmi kúrò lọ́wọ́ gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ̀ tó yí i ká,+ Sólómọ́nì*+ ni orúkọ tí a máa pè é, màá sì fi àlàáfíà àti ìparọ́rọ́ jíǹkí Ísírẹ́lì ní ìgbà ayé rẹ̀.+ Sáàmù 72:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ní àkókò rẹ̀, àwọn olódodo yóò gbilẹ̀,*+Àlàáfíà yóò sì gbilẹ̀+ títí òṣùpá kò fi ní sí mọ́.
4 Àmọ́ ní báyìí, Jèhófà Ọlọ́run mi ti fún mi ní ìsinmi yí ká.+ Kò sí alátakò kankan, láburú kankan ò sì ṣẹlẹ̀.+
9 Wò ó! Wàá bí ọmọkùnrin kan+ tó máa jẹ́ ẹni àlàáfíà,* màá sì fún un ní ìsinmi kúrò lọ́wọ́ gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ̀ tó yí i ká,+ Sólómọ́nì*+ ni orúkọ tí a máa pè é, màá sì fi àlàáfíà àti ìparọ́rọ́ jíǹkí Ísírẹ́lì ní ìgbà ayé rẹ̀.+