Òwe 1:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 1 Òwe Sólómọ́nì,+ ọmọ Dáfídì,+ ọba Ísírẹ́lì:+ Oníwàásù 12:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Kì í ṣe pé akónijọ di ọlọ́gbọ́n nìkan ni, ó tún máa ń kọ́ àwọn èèyàn ní ohun tó mọ̀,+ ó ronú jinlẹ̀, ó sì wádìí fínnífínní, kí ó lè kó ọ̀pọ̀lọpọ̀ òwe jọ.*+
9 Kì í ṣe pé akónijọ di ọlọ́gbọ́n nìkan ni, ó tún máa ń kọ́ àwọn èèyàn ní ohun tó mọ̀,+ ó ronú jinlẹ̀, ó sì wádìí fínnífínní, kí ó lè kó ọ̀pọ̀lọpọ̀ òwe jọ.*+