Òwe 6:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Tọ èèrà lọ, ìwọ ọ̀lẹ;+Kíyè sí àwọn ọ̀nà rẹ̀, kí o sì gbọ́n. Òwe 30:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Àwọn èèrà jẹ́ ẹ̀dá* tí kò lágbára,Síbẹ̀, wọ́n ń kó oúnjẹ wọn jọ nígbà ẹ̀ẹ̀rùn.+