2 Kíróníkà 2:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Yàtọ̀ síyẹn, Sólómọ́nì ránṣẹ́ sí Hírámù+ ọba Tírè pé: “Ohun tí o ṣe fún Dáfídì bàbá mi nígbà tí o kó igi kédárì ránṣẹ́ sí i láti fi kọ́ ilé* tí á máa gbé ni kí o ṣe fún mi.+
3 Yàtọ̀ síyẹn, Sólómọ́nì ránṣẹ́ sí Hírámù+ ọba Tírè pé: “Ohun tí o ṣe fún Dáfídì bàbá mi nígbà tí o kó igi kédárì ránṣẹ́ sí i láti fi kọ́ ilé* tí á máa gbé ni kí o ṣe fún mi.+