-
2 Kíróníkà 2:11, 12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Hírámù ọba Tírè wá kọ̀wé ránṣẹ́ sí Sólómọ́nì pé: “Nítorí pé Jèhófà nífẹ̀ẹ́ àwọn èèyàn rẹ̀, ó fi ọ́ ṣe ọba wọn.” 12 Hírámù sì sọ pé: “Ìyìn ni fún Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì, ẹni tó dá ọ̀run àti ayé, nítorí ó ti fún Ọba Dáfídì ní ọlọ́gbọ́n ọmọ+ tó ní làákàyè àti òye,+ tó máa kọ́ ilé fún Jèhófà àti fún ìjọba òun fúnra rẹ̀.
-