1 Kíróníkà 22:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Àwọn òṣìṣẹ́ púpọ̀ wà pẹ̀lú rẹ, ìyẹn àwọn agbẹ́kùúta, àwọn oníṣẹ́ òkúta+ àti àwọn oníṣẹ́ igi pẹ̀lú onírúurú àwọn akọ́ṣẹ́mọṣẹ́.+
15 Àwọn òṣìṣẹ́ púpọ̀ wà pẹ̀lú rẹ, ìyẹn àwọn agbẹ́kùúta, àwọn oníṣẹ́ òkúta+ àti àwọn oníṣẹ́ igi pẹ̀lú onírúurú àwọn akọ́ṣẹ́mọṣẹ́.+