1 Àwọn Ọba 9:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ọgọ́rùn-ún márùn-ún ó lé àádọ́ta (550) olórí àwọn alábòójútó ló ń darí iṣẹ́ Sólómọ́nì, àwọn ló sì ń darí àwọn òṣìṣẹ́.+
23 Ọgọ́rùn-ún márùn-ún ó lé àádọ́ta (550) olórí àwọn alábòójútó ló ń darí iṣẹ́ Sólómọ́nì, àwọn ló sì ń darí àwọn òṣìṣẹ́.+