Ìfihàn 21:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ògiri ìlú náà tún ní òkúta ìpìlẹ̀ méjìlá (12), orúkọ méjìlá (12) àwọn àpọ́sítélì méjìlá (12)+ ti Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà sì wà lára wọn.
14 Ògiri ìlú náà tún ní òkúta ìpìlẹ̀ méjìlá (12), orúkọ méjìlá (12) àwọn àpọ́sítélì méjìlá (12)+ ti Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà sì wà lára wọn.