-
Ìsíkíẹ́lì 41:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Ẹnu ọ̀nà kan wà láàárín àwọn yàrá ẹ̀gbẹ́ àti àyè tó wà ní apá àríwá, ẹnu ọ̀nà mìíràn sì wà ní apá gúúsù. Fífẹ̀ àyè náà jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ márùn-ún yí ká.
-