1 Àwọn Ọba 6:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ó tún mọ ògiri kan ti ògiri ilé náà; ògiri náà yí àwọn ògiri ilé náà ká, ìyẹn ti tẹ́ńpìlì* àti ti yàrá inú lọ́hùn-ún,+ ó sì ṣe àwọn yàrá ẹ̀gbẹ́ sínú rẹ̀ yí ká.+
5 Ó tún mọ ògiri kan ti ògiri ilé náà; ògiri náà yí àwọn ògiri ilé náà ká, ìyẹn ti tẹ́ńpìlì* àti ti yàrá inú lọ́hùn-ún,+ ó sì ṣe àwọn yàrá ẹ̀gbẹ́ sínú rẹ̀ yí ká.+