-
1 Àwọn Ọba 7:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Àwọn iṣẹ́ ọnà tó rí bí akèrègbè+ wà nísàlẹ̀ ẹnu rẹ̀ yí ká, mẹ́wàá nínú ìgbọ̀nwọ́ kan, wọ́n yí Òkun náà po, ìlà méjì àwọn iṣẹ́ ọnà tó rí bí akèrègbè náà ni ó ṣe mọ́ ọn lára.
-