2 Kíróníkà 4:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ó wá ṣe àgbàlá+ àwọn àlùfáà+ àti àgbàlá ńlá* pẹ̀lú àwọn ilẹ̀kùn àgbàlá náà,+ ó sì fi bàbà bo àwọn ilẹ̀kùn wọn.
9 Ó wá ṣe àgbàlá+ àwọn àlùfáà+ àti àgbàlá ńlá* pẹ̀lú àwọn ilẹ̀kùn àgbàlá náà,+ ó sì fi bàbà bo àwọn ilẹ̀kùn wọn.