-
1 Àwọn Ọba 7:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Ọba Sólómọ́nì ránṣẹ́ sí Hírámù,+ ó sì wá láti Tírè.
-
-
2 Kíróníkà 2:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Wò ó, mo ti rán ọkùnrin ọ̀jáfáfá oníṣẹ́ ọnà kan sí ọ, ó ní òye, Hiramu-ábì+ ni orúkọ rẹ̀,
-