Sáàmù 71:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ètè mi yóò máa kígbe ayọ̀ bí mo ṣe ń kọ orin ìyìn sí ọ,+Nítorí o gba ẹ̀mí mi là.*+ Sáàmù 103:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ó gba ẹ̀mí mi pa dà látinú kòtò,*+Ó sì fi ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ àti àánú dé mi ládé,+