Ẹ́kísódù 37:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Lẹ́yìn náà, ó fi ògidì wúrà ṣe fìtílà rẹ̀ méje+ àti àwọn ìpaná* rẹ̀ àti àwọn ìkóná rẹ̀.