Léfítíkù 16:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 “Kó wá mú ìkóná+ tí ẹyin iná tó ń jó látorí pẹpẹ+ níwájú Jèhófà kún inú rẹ̀, pẹ̀lú ẹ̀kúnwọ́ tùràrí onílọ́fínńdà+ méjì tó dáa, kó sì kó wọn wá sẹ́yìn aṣọ ìdábùú.+
12 “Kó wá mú ìkóná+ tí ẹyin iná tó ń jó látorí pẹpẹ+ níwájú Jèhófà kún inú rẹ̀, pẹ̀lú ẹ̀kúnwọ́ tùràrí onílọ́fínńdà+ méjì tó dáa, kó sì kó wọn wá sẹ́yìn aṣọ ìdábùú.+