2 Kíróníkà 5:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Níkẹyìn, Sólómọ́nì parí gbogbo iṣẹ́ ilé Jèhófà tó yẹ ní ṣíṣe.+ Lẹ́yìn náà, Sólómọ́nì kó àwọn ohun tí Dáfídì bàbá rẹ̀ ti yà sí mímọ́ wọlé,+ ó kó fàdákà, wúrà àti gbogbo ohun èlò wá sínú ibi ìṣúra ilé Ọlọ́run tòótọ́.+
5 Níkẹyìn, Sólómọ́nì parí gbogbo iṣẹ́ ilé Jèhófà tó yẹ ní ṣíṣe.+ Lẹ́yìn náà, Sólómọ́nì kó àwọn ohun tí Dáfídì bàbá rẹ̀ ti yà sí mímọ́ wọlé,+ ó kó fàdákà, wúrà àti gbogbo ohun èlò wá sínú ibi ìṣúra ilé Ọlọ́run tòótọ́.+