-
Ẹ́kísódù 25:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 O máa ki àwọn ọ̀pá náà bọ inú àwọn òrùka tó wà ní ẹ̀gbẹ́ méjèèjì Àpótí náà, kí ẹ lè máa fi gbé Àpótí náà.
-
-
Ẹ́kísódù 37:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Ó wá fi igi bọn-ọ̀n-ní ṣe àwọn ọ̀pá, ó sì fi wúrà bò wọ́n.+
-