5 Nínú gbogbo àwọn ọmọ mi, torí àwọn ọmọ tí Jèhófà fún mi pọ̀,+ ó yan Sólómọ́nì+ ọmọ mi láti jókòó sórí ìtẹ́ ìjọba Jèhófà lórí Ísírẹ́lì.+
6 “Ó sọ fún mi pé, ‘Sólómọ́nì ọmọ rẹ ló máa kọ́ ilé mi àti àwọn àgbàlá mi, nítorí mo ti yàn án ṣe ọmọ mi, màá sì di bàbá rẹ̀.+