2 Sámúẹ́lì 15:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Gbogbo àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ tí wọ́n jọ kúrò* àti gbogbo àwọn Kérétì àti àwọn Pẹ́lẹ́tì+ àti àwọn ará Gátì,+ ọgọ́rùn-ún mẹ́fà (600) ọkùnrin tí wọ́n tẹ̀ lé e láti Gátì,+ sì ń kọjá bí ọba ti ń yẹ̀ wọ́n wò.* 1 Kíróníkà 18:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Bẹnáyà ọmọ Jèhóádà ni olórí àwọn Kérétì+ àti àwọn Pẹ́lẹ́tì.+ Àwọn ọmọkùnrin Dáfídì ló sì wà ní ipò iwájú lẹ́yìn ọba.
18 Gbogbo àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ tí wọ́n jọ kúrò* àti gbogbo àwọn Kérétì àti àwọn Pẹ́lẹ́tì+ àti àwọn ará Gátì,+ ọgọ́rùn-ún mẹ́fà (600) ọkùnrin tí wọ́n tẹ̀ lé e láti Gátì,+ sì ń kọjá bí ọba ti ń yẹ̀ wọ́n wò.*
17 Bẹnáyà ọmọ Jèhóádà ni olórí àwọn Kérétì+ àti àwọn Pẹ́lẹ́tì.+ Àwọn ọmọkùnrin Dáfídì ló sì wà ní ipò iwájú lẹ́yìn ọba.