Sáàmù 86:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Jèhófà, kọ́ mi ní ọ̀nà rẹ.+ Èmi yóò máa rìn nínú òtítọ́ rẹ.+ Fún mi ní ọkàn tó pa pọ̀* kí n lè máa bẹ̀rù orúkọ rẹ.+ Sáàmù 119:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Mú kí ọkàn mi máa fà sí àwọn ìránnilétí rẹ,Kó má ṣe fà sí èrè tí kò tọ́.*+ 2 Tẹsalóníkà 3:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Kí Olúwa máa darí ọkàn yín sínú ìfẹ́ Ọlọ́run+ àti sínú ìfaradà+ fún Kristi.
11 Jèhófà, kọ́ mi ní ọ̀nà rẹ.+ Èmi yóò máa rìn nínú òtítọ́ rẹ.+ Fún mi ní ọkàn tó pa pọ̀* kí n lè máa bẹ̀rù orúkọ rẹ.+