Ẹ́sírà 6:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Lẹ́yìn náà, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, àwọn àlùfáà àti àwọn ọmọ Léfì + pẹ̀lú àwọn tó wà nígbèkùn tẹ́lẹ̀ fi ìdùnnú ṣe ayẹyẹ ṣíṣí* ilé Ọlọ́run yìí. Nehemáyà 12:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Nígbà ayẹyẹ ṣíṣí ògiri Jerúsálẹ́mù, wọ́n wá àwọn ọmọ Léfì, wọ́n sì mú wọn wá sí Jerúsálẹ́mù láti gbogbo ibi tí wọ́n ń gbé kí wọ́n lè ṣe ayẹyẹ náà tayọ̀tayọ̀, pẹ̀lú orin ọpẹ́,+ pẹ̀lú síńbálì* àti àwọn ohun ìkọrin olókùn tín-ín-rín àti háàpù.
16 Lẹ́yìn náà, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, àwọn àlùfáà àti àwọn ọmọ Léfì + pẹ̀lú àwọn tó wà nígbèkùn tẹ́lẹ̀ fi ìdùnnú ṣe ayẹyẹ ṣíṣí* ilé Ọlọ́run yìí.
27 Nígbà ayẹyẹ ṣíṣí ògiri Jerúsálẹ́mù, wọ́n wá àwọn ọmọ Léfì, wọ́n sì mú wọn wá sí Jerúsálẹ́mù láti gbogbo ibi tí wọ́n ń gbé kí wọ́n lè ṣe ayẹyẹ náà tayọ̀tayọ̀, pẹ̀lú orin ọpẹ́,+ pẹ̀lú síńbálì* àti àwọn ohun ìkọrin olókùn tín-ín-rín àti háàpù.