Jẹ́nẹ́sísì 15:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ní ọjọ́ yẹn, Jèhófà bá Ábúrámù dá májẹ̀mú+ kan pé: “Ọmọ* rẹ ni èmi yóò fún ní ilẹ̀ yìí,+ láti odò Íjíbítì dé odò ńlá náà, ìyẹn odò Yúfírétì:+ Nọ́ńbà 34:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Kí ààlà náà yí gba Àfonífojì Íjíbítì láti Ásímónì, kó sì parí sí Òkun.*+ Nọ́ńbà 34:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Kí ẹ pààlà yín láti Òkè Hóórì dé Lebo-hámátì,*+ kí ààlà náà sì parí sí Sédádì.+
18 Ní ọjọ́ yẹn, Jèhófà bá Ábúrámù dá májẹ̀mú+ kan pé: “Ọmọ* rẹ ni èmi yóò fún ní ilẹ̀ yìí,+ láti odò Íjíbítì dé odò ńlá náà, ìyẹn odò Yúfírétì:+