Diutarónómì 28:37 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 37 O máa di ohun tó ń dẹ́rù bani, ẹni ẹ̀gàn* àti ẹni ẹ̀sín láàárín gbogbo àwọn tí Jèhófà bá lé ọ lọ bá.+ Sáàmù 44:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 O sọ wá di ẹni ẹ̀gàn* láàárín àwọn orílẹ̀-èdè,+Ẹni tí àwọn èèyàn ń rí, tí wọ́n ń mi orí.
37 O máa di ohun tó ń dẹ́rù bani, ẹni ẹ̀gàn* àti ẹni ẹ̀sín láàárín gbogbo àwọn tí Jèhófà bá lé ọ lọ bá.+