ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóṣúà 16:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Ilẹ̀ tí wọ́n fi kèké pín*+ fún àwọn àtọmọdọ́mọ Jósẹ́fù+ bẹ̀rẹ̀ láti Jọ́dánì ní Jẹ́ríkò dé ibi omi tó wà lápá ìlà oòrùn Jẹ́ríkò, ó gba inú aginjù láti Jẹ́ríkò lọ sí agbègbè olókè Bẹ́tẹ́lì.+

  • Jóṣúà 16:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 ó wá lọ sí ìsàlẹ̀ lápá ìwọ̀ oòrùn dé ààlà àwọn ọmọ Jáfílétì títí lọ dé ààlà Bẹti-hórónì+ Ìsàlẹ̀ àti Gésérì,+ ó sì parí sí òkun.

  • 2 Kíróníkà 8:4-6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Lẹ́yìn náà, ó kọ́ Tádímórì ní aginjù* àti gbogbo àwọn ìlú tí ó ń kó nǹkan pa mọ́ sí,+ èyí tó kọ́ sí Hámátì.+ 5 Ó tún kọ́ Bẹti-hórónì Òkè+ àti Bẹti-hórónì Ìsàlẹ̀,+ àwọn ìlú aláàbò tó ní ògiri àti àwọn ẹnubodè pẹ̀lú ọ̀pá ìdábùú. 6 Bákan náà, ó kọ́ Báálátì+ pẹ̀lú gbogbo àwọn ìlú tó ń kó nǹkan pa mọ́ sí, gbogbo àwọn ìlú kẹ̀kẹ́ ẹṣin,+ àwọn ìlú àwọn agẹṣin àti ohunkóhun tó wu Sólómọ́nì láti kọ́ sí Jerúsálẹ́mù, sí Lẹ́bánónì àti sí gbogbo ilẹ̀ tó ń ṣàkóso lé lórí.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́