Léfítíkù 25:39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 “‘Tí arákùnrin rẹ tó ń gbé nítòsí bá di aláìní, tó sì ní láti ta ara rẹ̀ fún ọ,+ má fipá mú un ṣe ẹrú.+
39 “‘Tí arákùnrin rẹ tó ń gbé nítòsí bá di aláìní, tó sì ní láti ta ara rẹ̀ fún ọ,+ má fipá mú un ṣe ẹrú.+