2 Kíróníkà 8:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Nítorí náà, gbogbo iṣẹ́ Sólómọ́nì wà létòlétò,* láti ọjọ́ tí wọ́n ti fi ìpìlẹ̀ ilé Jèhófà lélẹ̀+ títí ó fi parí. Bí ilé Jèhófà ṣe parí nìyẹn.+
16 Nítorí náà, gbogbo iṣẹ́ Sólómọ́nì wà létòlétò,* láti ọjọ́ tí wọ́n ti fi ìpìlẹ̀ ilé Jèhófà lélẹ̀+ títí ó fi parí. Bí ilé Jèhófà ṣe parí nìyẹn.+