-
1 Àwọn Ọba 1:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Níkẹyìn, Ádóníjà fi àgùntàn àti màlúù pẹ̀lú ẹran àbọ́sanra rúbọ+ lẹ́gbẹ̀ẹ́ òkúta Sóhélétì, èyí tó wà nítòsí Ẹn-rógélì, ó pe gbogbo àwọn arákùnrin rẹ̀ àwọn ọmọ ọba àti gbogbo ọkùnrin Júdà tí wọ́n jẹ́ ìránṣẹ́ ọba.
-