Òwe 8:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Aláyọ̀ ni ẹni tó ń fetí sí miTó ń jí wá sẹ́nu* ọ̀nà mi lójoojúmọ́,Tó ń dúró lẹ́gbẹ̀ẹ́ òpó ilẹ̀kùn mi;
34 Aláyọ̀ ni ẹni tó ń fetí sí miTó ń jí wá sẹ́nu* ọ̀nà mi lójoojúmọ́,Tó ń dúró lẹ́gbẹ̀ẹ́ òpó ilẹ̀kùn mi;