-
Nọ́ńbà 23:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Àwọn èèyàn yìí yóò dìde bíi kìnnìún,
Bíi kìnnìún ni yóò gbé ara rẹ̀ sókè.+
Kò ní dùbúlẹ̀ títí yóò fi jẹ ẹran tó bá mú
Tó sì máa mu ẹ̀jẹ̀ àwọn tó bá pa.”
-
-
Nọ́ńbà 24:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Ó ti dùbúlẹ̀, ó sùn sílẹ̀ bíi kìnnìún,
Bíi kìnnìún, ta ló láyà láti jí i?
Ìbùkún ni fún àwọn tó ń súre fún ọ,
Ègún sì ni fún àwọn tó ń gégùn-ún+ fún ọ.”
-