ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 10:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Àwọn ọmọ Jáfánì ni Élíṣáhì,+ Táṣíṣì,+ Kítímù+ àti Dódánímù.

  • Sáàmù 72:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Àwọn ọba Táṣíṣì àti ti àwọn erékùṣù yóò máa san ìṣákọ́lẹ̀.*+

      Àwọn ọba Ṣébà àti ti Sébà yóò mú ẹ̀bùn wá.+

  • Ìsíkíẹ́lì 27:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 “‘“Táṣíṣì+ bá ọ dòwò pọ̀ torí ọrọ̀ rẹ pọ̀ rẹpẹtẹ.+ Fàdákà, irin, tánganran àti òjé ni wọ́n fi ṣe pàṣípààrọ̀ ọjà lọ́dọ̀ rẹ.+

  • Jónà 1:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Àmọ́ Jónà fẹ́ lọ sí Táṣíṣì, kó lè sá fún Jèhófà. Torí náà, ó gbéra, ó lọ sí Jópà, ó sì rí ọkọ̀ òkun kan tó ń lọ sí Táṣíṣì. Ó san owó ọkọ̀, ó sì wọlé láti bá wọn lọ sí Táṣíṣì, kó lè sá fún Jèhófà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́