-
1 Àwọn Ọba 2:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Ni Ọba Sólómọ́nì bá fi Jèhófà búra pé: “Kí Ọlọ́run fìyà jẹ mí gan-an, tí kò bá jẹ́ pé ohun tó máa gbẹ̀mí* Ádóníjà ló ń béèrè yìí.
-