2 Kíróníkà 12:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Wòlíì Ṣemáyà+ wá sọ́dọ̀ Rèhóbóámù àti àwọn ìjòyè Júdà tí wọ́n kóra jọ sí Jerúsálẹ́mù nítorí Ṣíṣákì, ó sì sọ fún wọn pé: “Ohun tí Jèhófà sọ nìyí, ‘Ẹ ti fi mí sílẹ̀, èmi náà ti fi yín sílẹ̀+ sí ọwọ́ Ṣíṣákì.’”
5 Wòlíì Ṣemáyà+ wá sọ́dọ̀ Rèhóbóámù àti àwọn ìjòyè Júdà tí wọ́n kóra jọ sí Jerúsálẹ́mù nítorí Ṣíṣákì, ó sì sọ fún wọn pé: “Ohun tí Jèhófà sọ nìyí, ‘Ẹ ti fi mí sílẹ̀, èmi náà ti fi yín sílẹ̀+ sí ọwọ́ Ṣíṣákì.’”