-
2 Sámúẹ́lì 20:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Ámásà kò fura sí idà ọwọ́ Jóábù; Jóábù fi idà náà gún un ní ikùn,+ ìfun rẹ̀ sì tú síta sórí ilẹ̀. Kò gún un lẹ́ẹ̀mejì, ìgbà kan péré ti tó láti pa á. Lẹ́yìn náà, Jóábù àti Ábíṣáì ẹ̀gbọ́n rẹ̀ lépa Ṣébà ọmọ Bíkíráì.
-
-
1 Kíróníkà 2:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Ábígẹ́lì bí Ámásà,+ bàbá Ámásà sì ni Jétà ọmọ Íṣímáẹ́lì.
-