ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 14:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Bí Ábúrámù ṣe gbọ́ pé wọ́n ti mú mọ̀lẹ́bí*+ òun lẹ́rú, ó kó àwọn ọkùnrin tó ti kọ́ ní ogun jíjà, àwọn ọgọ́rùn-ún mẹ́ta ó lé méjìdínlógún (318) ìránṣẹ́ tí wọ́n bí sínú agbo ilé rẹ̀, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í lé wọn títí dé Dánì.+

  • Diutarónómì 34:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 34 Mósè wá kúrò ní aṣálẹ̀ tó tẹ́jú ní Móábù lọ sí Òkè Nébò,+ sí orí Písígà,+ tó dojú kọ Jẹ́ríkò.+ Jèhófà sì fi gbogbo ilẹ̀ náà hàn án, láti Gílíádì títí dé Dánì+

  • Àwọn Onídàájọ́ 18:29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 Bákan náà, wọ́n sọ ìlú náà ní Dánì,+ ìyẹn Dánì orúkọ bàbá wọn, ẹni tí wọ́n bí fún Ísírẹ́lì.+ Àmọ́ Láíṣì ni ìlú náà ń jẹ́ tẹ́lẹ̀.+

  • Àwọn Onídàájọ́ 20:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Nígbà tó yá, gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kúrò ní Dánì+ títí lọ dé Bíá-ṣébà àti ilẹ̀ Gílíádì,+ gbogbo àpéjọ náà sì kóra jọ sójú kan* níwájú Jèhófà ní Mísípà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́