1 Àwọn Ọba 12:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Jèróbóámù tún dá àjọyọ̀ kan sílẹ̀ ní oṣù kẹjọ, ní ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún oṣù náà, bí àjọyọ̀ tó wà ní Júdà.+ Ó rú ẹbọ sí àwọn ère ọmọ màlúù tó ṣe sórí àwọn pẹpẹ tó ṣe ní Bẹ́tẹ́lì,+ ó sì yan àwọn àlùfáà ní Bẹ́tẹ́lì fún àwọn ibi gíga tó ṣe. Émọ́sì 3:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 ‘Ní ọjọ́ tí màá mú kí Ísírẹ́lì jíhìn nítorí ìdìtẹ̀* rẹ̀,+Ni màá mú kí àwọn pẹpẹ Bẹ́tẹ́lì pẹ̀lú jíhìn;+A ó ṣẹ́ àwọn ìwo pẹpẹ náà, wọ́n á sì já bọ́ sílẹ̀.+
32 Jèróbóámù tún dá àjọyọ̀ kan sílẹ̀ ní oṣù kẹjọ, ní ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún oṣù náà, bí àjọyọ̀ tó wà ní Júdà.+ Ó rú ẹbọ sí àwọn ère ọmọ màlúù tó ṣe sórí àwọn pẹpẹ tó ṣe ní Bẹ́tẹ́lì,+ ó sì yan àwọn àlùfáà ní Bẹ́tẹ́lì fún àwọn ibi gíga tó ṣe.
14 ‘Ní ọjọ́ tí màá mú kí Ísírẹ́lì jíhìn nítorí ìdìtẹ̀* rẹ̀,+Ni màá mú kí àwọn pẹpẹ Bẹ́tẹ́lì pẹ̀lú jíhìn;+A ó ṣẹ́ àwọn ìwo pẹpẹ náà, wọ́n á sì já bọ́ sílẹ̀.+