-
2 Àwọn Ọba 6:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Nígbà tí àwọn ará Síríà náà wá bá a, Èlíṣà gbàdúrà sí Jèhófà, ó sì sọ pé: “Jọ̀ọ́, bu ìfọ́jú lu orílẹ̀-èdè yìí.”+ Nítorí náà, ó bu ìfọ́jú lù wọ́n bí Èlíṣà ṣe béèrè.
-