ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Àwọn Ọba 13:30
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 30 Torí náà, ó sin òkú náà sínú ibojì ti ara rẹ̀, wọ́n sì ń sunkún nítorí rẹ̀, wọ́n ń sọ pé: “Ó mà ṣe o, arákùnrin mi!”

  • 2 Àwọn Ọba 23:17, 18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Lẹ́yìn náà, ó sọ pé: “Èwo ni òkúta sàréè tí mò ń wò níbẹ̀ yẹn?” Àwọn èèyàn ìlú náà bá sọ fún un pé: “Sàréè èèyàn Ọlọ́run tòótọ́ tó wá láti Júdà+ ni, ẹni tó sọ àsọtẹ́lẹ̀ àwọn ohun tí o ṣe sí pẹpẹ tó wà ní Bẹ́tẹ́lì.” 18 Nítorí náà, ó sọ pé: “Kí ẹnikẹ́ni má fọwọ́ kan egungun rẹ̀, ẹ fi sílẹ̀ bó ṣe wà.” Torí náà, wọn ò fọwọ́ kan egungun rẹ̀, bẹ́ẹ̀ sì ni wọ́n ò fọwọ́ kan egungun wòlíì tó wá láti Samáríà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́