-
2 Kíróníkà 12:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Ọba Rèhóbóámù mú kí ipò rẹ̀ fìdí múlẹ̀ ní Jerúsálẹ́mù, ó sì ń jọba nìṣó; ẹni ọdún mọ́kànlélógójì (41) ni Rèhóbóámù nígbà tó di ọba, ó sì fi ọdún mẹ́tàdínlógún (17) jọba ní Jerúsálẹ́mù, ìlú tí Jèhófà yàn nínú gbogbo ẹ̀yà Ísírẹ́lì láti fi orúkọ rẹ̀ sí. Orúkọ ìyá ọba ni Náámà, ọmọ Ámónì sì ni.+
-