-
1 Àwọn Ọba 16:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Torí náà, màá gbá Bááṣà àti ilé rẹ̀ dà nù bí ẹni gbálẹ̀, màá sì ṣe ilé rẹ̀ bí ilé Jèróbóámù+ ọmọ Nébátì.
-
-
1 Àwọn Ọba 16:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Bí Símírì ṣe pa gbogbo ilé Bááṣà rẹ́ nìyẹn, bí ọ̀rọ̀ tí Jèhófà gbẹnu wòlíì Jéhù kéde sórí Bááṣà.+
-