1 Àwọn Ọba 16:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Jèhófà tún gbẹnu wòlíì Jéhù ọmọ Hánáánì kéde ìdájọ́ sórí Bááṣà àti ilé rẹ̀, nítorí gbogbo ìwà búburú tí ó hù ní ojú Jèhófà, tí ó fi iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀ mú un bínú, bí ilé Jèróbóámù àti nítorí pé ó ṣá a* balẹ̀.+
7 Jèhófà tún gbẹnu wòlíì Jéhù ọmọ Hánáánì kéde ìdájọ́ sórí Bááṣà àti ilé rẹ̀, nítorí gbogbo ìwà búburú tí ó hù ní ojú Jèhófà, tí ó fi iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀ mú un bínú, bí ilé Jèróbóámù àti nítorí pé ó ṣá a* balẹ̀.+