-
1 Àwọn Ọba 15:33Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
33 Ní ọdún kẹta Ásà ọba Júdà, Bááṣà ọmọ Áhíjà di ọba lórí gbogbo Ísírẹ́lì ní Tírísà, ó sì fi ọdún mẹ́rìnlélógún (24) ṣàkóso.+
-