-
Jóṣúà 19:44Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
44 Élétékè, Gíbétónì,+ Báálátì,
-
-
Jóṣúà 19:48Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
48 Èyí ni ogún ẹ̀yà Dánì ní ìdílé-ìdílé. Èyí sì ni àwọn ìlú náà pẹ̀lú àwọn ìgbèríko wọn.
-
-
Jóṣúà 21:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Wọ́n fi kèké pín àwọn ìlú fún àwọn ìdílé ọmọ Kóhátì yòókù nínú àwọn ọmọ Léfì látinú ìpín ẹ̀yà Éfúrémù.
-
-
Jóṣúà 21:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Látinú ìpín ẹ̀yà Dánì: Élítékè pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀, Gíbétónì pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀,
-
-
1 Àwọn Ọba 15:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 Bááṣà ọmọ Áhíjà ará ilé Ísákà dìtẹ̀ mọ́ ọn, Bááṣà sì pa á ní Gíbétónì+ tó jẹ́ ti àwọn Filísínì, nígbà tí Nádábù àti gbogbo Ísírẹ́lì dó ti Gíbétónì.
-