2 Àwọn Ọba 10:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Lẹ́yìn ìyẹn, Jéhù ránṣẹ́ káàkiri gbogbo Ísírẹ́lì, gbogbo àwọn tó ń jọ́sìn Báálì sì wá. Kò sí ìkankan lára wọn tó ṣẹ́ kù tí kò wá. Wọ́n wọ ilé* Báálì,+ ilé Báálì sì kún láti ìpẹ̀kun kan dé ìpẹ̀kun kejì. 2 Àwọn Ọba 10:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Wọ́n ti ọwọ̀n òrìṣà Báálì ṣubú,+ wọ́n wó ilé Báálì+ lulẹ̀, wọ́n sì sọ ọ́ di ilé ìyàgbẹ́, bó ṣe wà títí di òní yìí.
21 Lẹ́yìn ìyẹn, Jéhù ránṣẹ́ káàkiri gbogbo Ísírẹ́lì, gbogbo àwọn tó ń jọ́sìn Báálì sì wá. Kò sí ìkankan lára wọn tó ṣẹ́ kù tí kò wá. Wọ́n wọ ilé* Báálì,+ ilé Báálì sì kún láti ìpẹ̀kun kan dé ìpẹ̀kun kejì.
27 Wọ́n ti ọwọ̀n òrìṣà Báálì ṣubú,+ wọ́n wó ilé Báálì+ lulẹ̀, wọ́n sì sọ ọ́ di ilé ìyàgbẹ́, bó ṣe wà títí di òní yìí.