Jóṣúà 22:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Lẹ́yìn náà, àwọn ọmọ Rúbẹ́nì, àwọn ọmọ Gádì àti ààbọ̀ ẹ̀yà Mánásè kúrò lọ́dọ̀ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì yòókù, ní Ṣílò, ní ilẹ̀ Kénáánì, wọ́n sì pa dà sí ilẹ̀ Gílíádì,+ ilẹ̀ tí wọ́n jogún tí wọ́n sì ń gbé bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ nípasẹ̀ Mósè.+
9 Lẹ́yìn náà, àwọn ọmọ Rúbẹ́nì, àwọn ọmọ Gádì àti ààbọ̀ ẹ̀yà Mánásè kúrò lọ́dọ̀ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì yòókù, ní Ṣílò, ní ilẹ̀ Kénáánì, wọ́n sì pa dà sí ilẹ̀ Gílíádì,+ ilẹ̀ tí wọ́n jogún tí wọ́n sì ń gbé bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ nípasẹ̀ Mósè.+