2 Sámúẹ́lì 5:4, 5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ẹni ọgbọ̀n (30) ọdún ni Dáfídì nígbà tí ó di ọba, ogójì (40) ọdún+ ló sì fi ṣàkóso. 5 Ọdún méje àti oṣù mẹ́fà ló fi jọba lórí Júdà ní Hébúrónì, ó sì fi ọdún mẹ́tàlélọ́gbọ̀n (33) ṣàkóso lórí gbogbo Ísírẹ́lì àti Júdà ní Jerúsálẹ́mù.+
4 Ẹni ọgbọ̀n (30) ọdún ni Dáfídì nígbà tí ó di ọba, ogójì (40) ọdún+ ló sì fi ṣàkóso. 5 Ọdún méje àti oṣù mẹ́fà ló fi jọba lórí Júdà ní Hébúrónì, ó sì fi ọdún mẹ́tàlélọ́gbọ̀n (33) ṣàkóso lórí gbogbo Ísírẹ́lì àti Júdà ní Jerúsálẹ́mù.+